Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Orin 85: Yìn Ọlọ́run Ẹlẹ́dàá Wa
Give to Our God Immortal Praise
Yìn Ọlọ́run Ẹlẹ́dá wa,
Àánú àt' òótọ́ l' ọ̀nà Rẹ
T' Ọlọ́run wa l' oore-ọ̀fẹ́
Rọ̀hìn àánú Rẹ 'nú orin.
K' òkìkí Ọba 'wọn Ọba,
D' Olú àwọn ọ̀run l' adé;
Àánú Rẹ yóò wà títí láé,
'Gbà tí kò ní sí orú mọ́.
Ó rán 'Mọ Rẹ̀ pẹ̀l' agbára,
Ìgbàlà k' rò n' n' ebi àt' ikú;
T' Ọlọ́run wa l' oore-ọ̀fẹ́,
Rọ̀yìn àánú Rẹ 'nú orin.
Ó ń tọ́ wa l' ayé osì yìí,
Ó ń sìn wa rẹ ìdí 'tẹ́ Rẹ;
Àánú Rẹ, yóò d' rò títí láé
Gb' ayé osì yìí k' yóò sí mọ́.