Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 618: Ṣẹ̀ṣẹ̀ Ni 'Nú Mi Dùn

Just Now My Heart Is Glad

Ṣẹ̀ṣẹ̀ ni 'nú mi dùn,
Ayọ̀ kún 'nú ọkàn mi;
Ṣẹ̀ṣẹ̀ ni 'nú mi dùn,
Ayọ̀ kún 'nú ọkàn mi;
'Tórí mo ní Jésù
Ayọ̀ kún 'nú ọkàn mi;
'Tórí mo ní Jésù l' Olúwa;
Ayọ̀ kún 'nú ọkàn mi.