Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 617: Ṣe Ni Máa Dúpẹ́

This Is What I Will Continually Give Thanks For

Ṣe ni máa dúpẹ́
Ṣe ni máa yìn Ọ o
Àìníyè l' oore Jésù
Ṣe ni máa dúpẹ́ Bàbá.