Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Orin 607: Ó Yẹ Kí Ẹsẹ̀ Mi Máa Jó
My Feet Ought To Always Dance
Ó yẹ k' ẹsẹ̀ mi máa jó
Ó yẹ k' ọkàn mi máa yọ
Ó yẹ k' ẹnu mi máa kọrin ògo
Olúwa ṣeun ayọ̀ fún mi.
Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
My Feet Ought To Always Dance
Ó yẹ k' ẹsẹ̀ mi máa jó
Ó yẹ k' ọkàn mi máa yọ
Ó yẹ k' ẹnu mi máa kọrin ògo
Olúwa ṣeun ayọ̀ fún mi.