Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 606: O Ṣe E, O Ṣe E, O Ṣe E

Thank You, Thank You, Thank You

O ṣe e, O ṣe e, O ṣe e
Oore Rẹ lórí mi;
Àánú Rẹ dá mi sí o
O má ṣe Ọba ìyè.