Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Orin 604: O Mú Mi Wá L' Ayé O Ṣeun O
You Brought Me Into The World Thank You
O mú mi wá l' ayé, O ṣeun o
O mú mi wá l' ayé, O ṣeun o
Ọ̀pọ̀ l' ó fẹ́ d' ọjọ́ oní o tó jẹ́ wí pé
Àìsàn t' ayé sọ pé kò tó nǹkan
L' ó mú wọn lọ.
O mú mi wá l' ayé, O ṣeun o