Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 592: Jésù O Ṣeun O

Jesus Thank You

Jésù O ṣeun O,
Jésù O ṣeun O,
Jésù Olúwa O
Ọba atẹ́rẹrẹ k' árí ayé O
Jésù O ṣeun O.