Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 591: Jésù Nìkan L' Ó Mọ Bí 'Lé Mi Ti Rí

Only Jesus Knows What My Home Was Like

Jésù nìkan l' ó mọ bí 'lé mi ti rí
Òun ló tún 'lé mi ṣe
Tún 'lé mi ṣe
Tún 'lé mi ṣe
Jésù bá mi tún 'lé mi ṣe.

Jésù nìkan l' ó mọ b' ayé mi ti rí

Jésù nìkan l' ó mọ bí 'ṣẹ́ mi ti rí

Jésù nìkan l' ó mọ b' ọ̀nà mi ti rí