Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 589: Jésù Mi Ṣeun

Thank You My Jesus

Jésù mi ṣeun, ṣeun,
Ọlọ́run mi ṣeun, ṣeun;
Jésù mi ṣeun, ṣeun,
Ọlọ́run mi ṣeun, ṣeun;
Mo bẹ́rẹ̀ mọ́lẹ̀, mo gbé E ga,
Mo gbé Jésù mi géńgé;
Ọwọ́ mi l' òkè yaaya,
Mo k' alélúyà rẹpẹtẹ;
Jésù mi ṣeun ṣeun;
Ọlọ́run mi ṣeun, ṣeun.