Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Orin 578: Ẹ̀yin Aláàyè, Ẹ̀yin Aláàyè
You The Living
Ẹ̀yin aláàyè, ẹ̀yin aláàyè,
Ẹ lọ t' ayé ṣe,
Jésù mi d' ẹ̀hìn bò
Jésù mi d' ẹ̀hìn bò,
Jésù mi d' ẹ̀hìn bò,
Jésù mi d' ẹ̀hìn bò
Ẹ̀yin aláàyè
Ẹ lọ t' ayé ṣe,
Jésù mi d' ẹ̀hìn bò.