Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 568: A Ń Rẹ' Lé O

We Are Going Home

A ń rẹ' lé o, Olójọ́ oní o,
A ń rẹ 'lé o,
Gbogbo ọ̀rọ̀ tí a gbọ́
Nínú ilé mímọ́ Rẹ
Má ṣe jẹ́ k' ẹyẹ èṣù.
K' ó ó sá wọn jẹ l' òkàn wa.
A ń rẹ lé o, Olójọ́ oní o,
A ń rẹ 'lé o.