Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Orin 563: Y' Ojú Rẹ S' Olùgbàlà
Turn Your Eyes Upon Jesus
Y' ojú rẹ s' Olùgbàlà,
Wò ojú ìfẹ́ 'yànu Rẹ̀,
Àwọn ohun àfẹ́ ayé yìí yóò sá
Níwájú ìmọ́lẹ̀ ògo Rẹ̀.
Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Turn Your Eyes Upon Jesus
Y' ojú rẹ s' Olùgbàlà,
Wò ojú ìfẹ́ 'yànu Rẹ̀,
Àwọn ohun àfẹ́ ayé yìí yóò sá
Níwájú ìmọ́lẹ̀ ògo Rẹ̀.