Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 561: Wá Wọ 'Kọ̀ Ẹ̀yin Ọmọdé

Get On Board Little Children

Wá wọ 'kọ̀ ẹ̀yin ọmọdé,
Wá wọ 'kọ̀ ẹ̀yin ọmọdé,
Wá wọ 'kọ̀ ẹ̀yin ọmọdé,
Àáyè sì ń bẹ síbẹ̀.

Okò ìhìn-rere ń bọ̀ wá,
Mo ń gbáríwó nítòsí,
Mo ń gbọ́ b' irin ti ń lo 'rìn,
Ó ń sáré lọ tètè.