Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Orin 554: Okò Mi Wà L' Oj' Okun
My Ship Is On The Ocean
Okò mi wà l' oj' òkun,
Yóò gúnlé s' èbúté;
Ó ń lọ s' ọ̀dọ̀ Bàbá mi
Yóò gúnlé s' èbúté;
Ṣàá; dúró jẹ̀ẹ́,
Kò ní pẹ́ mọ́;
Yóò gún lé s' èbúté,
Ṣàá; dúró jẹ̀ẹ́,
Kò ní pẹ́ mọ́;
Yóò gúnlé s' èbúté;