Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 552: Óò Wà Láàyé

He Lives

Óò wà láàyé, Jésù Kríst' wà láàyé
Ó ń bá mi rìn, Ó sì ń tọ́ mi
L' ọ̀nà hihà ayé;
Ó wà láàyé, Ó fi 'gbàlà fún mi
Wọ́n ń bèrè bí mo ti ṣe mọ̀
Ó ń gbé 'nú ọkàn mi.