Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 550: Ó Ń Wọ Sílẹ̀, Ó Ń Wọ Sílẹ̀,

Running Over, Running Over

Ó ń wọ sílẹ̀, ó ń wọ sílẹ̀,
Aago mi kún ó sì ń wọ sílẹ̀,
Gbà tí Jésù wá mi rí,
Mo l' ayọ̀ lọ́pọ̀lọ́pọ̀,
Aago mi kún ó sì ń wọ sílẹ̀.