Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 548: Ó Jìn, Ó Sì Fẹ́

Deep And Wide

Ó jìn gan-an, Ó sì fẹ̀,
Ìsun kan ń sàn, ó jìn, ó sì fẹ̀;
Ó jìn gan-an, Ó sì fẹ̀,
Ìsun kan ń sàn, Ó jìn, Ó sì fẹ̀,
Ó jìn...Ó fẹ̀
Ìsun kan ń sàn,
Ó jìn, Ó sì fẹ̀.