Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Orin 547: N Ó Jẹ́rìí Rẹ F' Àwọn Elòmíràn
I'll Share My Faith
N ó jẹ́rìí Rẹ f' àwọn elòmíràn,
N ó jẹ́rìí Rẹ, àkókò fẹ́rẹ̀ẹ́ tán;
Gbà Jésù bá p' olùrànwọ́,
N ó fi 'tara dáhùn
N ó jẹ́rìí, jẹ́rìí Rẹ,
n' gbà gbogbo.
Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
I'll Share My Faith
N ó jẹ́rìí Rẹ f' àwọn elòmíràn,
N ó jẹ́rìí Rẹ, àkókò fẹ́rẹ̀ẹ́ tán;
Gbà Jésù bá p' olùrànwọ́,
N ó fi 'tara dáhùn
N ó jẹ́rìí, jẹ́rìí Rẹ,
n' gbà gbogbo.