Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Orin 546: Nín' Ọkàn Mi Ayọ̀ Wà Níbẹ̀
In My Heart There Rings A Melody
Nín' ọkàn mi ayọ̀ wà níbẹ̀,
Ayọ̀ wà níbẹ̀, àti orin ọ̀run;
Nín' ọkàn mi ayọ̀ wà níbẹ̀,
Ayọ̀ ìfẹ́ wà níbẹ̀.
Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
In My Heart There Rings A Melody
Nín' ọkàn mi ayọ̀ wà níbẹ̀,
Ayọ̀ wà níbẹ̀, àti orin ọ̀run;
Nín' ọkàn mi ayọ̀ wà níbẹ̀,
Ayọ̀ ìfẹ́ wà níbẹ̀.