Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 540: Mo Fẹ́ Múra Dé Bíbọ̀ Jésù Mi

I Want To Be Ready

Mo fẹ́ múra dé bíbọ̀ Jésù mi,
Mo fẹ́ múra dé bíbọ̀ Jésù mi,
Ayọ̀ ayé sá,
'Gbà mo ń dúró dé Ọ,
Pa mi mọ́ dé bíbọ̀ Rẹ̀.