Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 539: Láìpẹ́ A Ó R' Ọba Wa

Bye And Bye We'll See The King

Láìpẹ́ a ó r' Ọba wa,
Láìpẹ́ a ó r' Ọba wa,
Láìpẹ́ a ó r' Ọba wa,
Àwa yóò ṣe É l' Ọba,
Àwa yóò ṣe É l' Ọba,
Àwa yóò ṣe É l' Ọba,
Àwa yóò ṣe É l' Ọba.
Àwa yóò ṣe É l' Ọba