Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Orin 537: Kalfari Sọ Mi D' Ọ̀tun
Calvary Made Me Whole
Kálfárì sọ mi d' ọ̀tun,
Ìbànújẹ́ mi ti fò lọ;
Gbogb' omijé mi ni Jésù nù kúrò
Kálfárì sọ mi d' ọ̀tun.
Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Calvary Made Me Whole
Kálfárì sọ mi d' ọ̀tun,
Ìbànújẹ́ mi ti fò lọ;
Gbogb' omijé mi ni Jésù nù kúrò
Kálfárì sọ mi d' ọ̀tun.