Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 532: Jésù Fẹ́ràn Àwọn Ọmọdé

Jesus Loves The Little Children

Jésù fẹ́ràn àwọn ọmọdé,
Gbogb' ọmọ ilé ayé
Dúdú, funfun, oun pupa
Wọ́n jẹ́ ọmọ l' ojú Rẹ̀
Jésù fẹ́ràn àwọn ọmọdé ayé.