Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 531: Ìmọ́lẹ̀ Ọ̀run

Heavenly Sunshine

Ìmọ́lẹ̀ ọ̀run,
Ìmọ́lẹ̀ ọ̀run,
Fi ògo ọ̀run kún ọkàn mi;
Ìmọ́lẹ̀ ọ̀run,
Ìmọ́lẹ̀ ọ̀run,
Alelúyà, t' èmi ń Jésù.