Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Orin 530: Ilẹ̀kùn Kan Ni
One Door And Only One
Ilẹ̀kùn kan ni ṣùgbọ́n ó l' ojú méjì
Inú àt' òde; níbo n' Ìwọ wà?
Ilẹ̀kùn kan ni ṣùgbọ́n ó l' ojú méjì
Èmi wà 'nú 'lé níbo n' Ìwọ wà
Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
One Door And Only One
Ilẹ̀kùn kan ni ṣùgbọ́n ó l' ojú méjì
Inú àt' òde; níbo n' Ìwọ wà?
Ilẹ̀kùn kan ni ṣùgbọ́n ó l' ojú méjì
Èmi wà 'nú 'lé níbo n' Ìwọ wà