Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 525: F' Ìmọ́lẹ̀ Rẹ Hàn

Students Show Your Light

F' ìmọ́lẹ̀ rẹ hàn
F' ìmọ́lẹ̀ rẹ hàn
Fi 'mọ́lẹ̀ rẹ hàn
Tàn 'mọ́lẹ̀ rẹ ká gbogb' ayé,
A ń rìn nínú ìmọ́lẹ̀,
Tàn 'mọ́lẹ̀ rẹ ká 'lẹ̀
A ń rìn nínú ìmọ́lẹ̀.
Tàn 'mọ́lẹ̀ rẹ ká 'lẹ̀
Tàn 'mọ́lẹ̀ rẹ ká gbogb' ayé.