Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Orin 522: Èmi Ó Sọ Ọ D' Apẹja Ènìyàn
I Will Make You Fishers Of Men
Èmi ó sọ ọ d' apẹja ènìyàn
Apẹja ènìyàn, apẹja ènìyàn
Èmi ó sọ ọ d' apẹja ènìyàn
B' o ó bá tẹ̀ lé Mi
Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
I Will Make You Fishers Of Men
Èmi ó sọ ọ d' apẹja ènìyàn
Apẹja ènìyàn, apẹja ènìyàn
Èmi ó sọ ọ d' apẹja ènìyàn
B' o ó bá tẹ̀ lé Mi