Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 518: Báwo L' Ó Ti Dùn Tó

How Sweet My Saviour To Repose

Báwo l' ó ti dùn tó láti
Simi l' apá Jésù,
Agbára Rẹ̀ l' ó ń gbé mi rò
Ní wákàtí gbogbo.
Kó gbogbo àníyàn rẹ lé E
Kó gbogbo àníyàn rẹ lé E
Kó gbogbo àníyàn rẹ lé E
Nítorí ó ń ṣe ìtọ́jú rẹ.