Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 517: Baríká Ọjọ́ 'Bí Rẹ

Happy Birthday To You

Baríká ọjọ́ 'bí rẹ,
Baríká ọjọ́ 'bí rẹ,
Baríká ọjọ́ 'bí rẹ, (ọ̀rẹ́)
Baríká ọjọ́ 'bí rẹ.

Ọjọ́ 'bí ayọ̀ fún ọ
Ọjọ́ 'bí ayọ̀ fún ọ
Ọjọ́ 'bí ayọ̀ fún ọ (ọ̀rẹ́)
Ọjọ́ 'bí ayọ̀ fún ọ.