Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 513: Àmín - Àmín

Amen - Amen

Àmín, Àmín, Àmín, Àmín,
'Bùkún àt' ògo, ọgbọ́n, opẹ́,
Àt' ọlá àt' agbára
Fún Ọlọ́run wa
Láé àti láéláé. Àmín.