Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 496: Ọlọ́run R' Ọpẹ́ẹ̀rẹ̀ Ṣubú

God Sees The Little Sparrow Fall

Ọlọ́run r' ọpẹ́ẹ̀rẹ̀ ṣubú,
Ó dojú àánú Rẹ̀;
B' Ọlọ́run fẹ́ 'yẹ kékeré,
Mo mọ̀, Ó fẹ́ mi náà.

Ó fẹ́ mi náà, Ó fẹ́ mi náà,
Mo mọ̀, Ó fẹ́ mi náà,
'Tọr' Ó fẹ́ ohun kékeré,
Mo mọ̀, Ó fẹ́ mi náà.

Ó kún àwọn lílì igbẹ́,
Ó f' oòrùn fún lílì;
B' Ó bá fẹ́ 'tànná kékeré,
Mo mọ̀, Ó fẹ́ mi náà.

Ó fẹ́ mi náà, Ó fẹ́ mi náà,
Mo mọ̀, Ó fẹ́ mi náà,
'Tọr' Ó fẹ́ ohun kékeré,
Mo mọ̀, Ó fẹ́ mi náà.

Ó dá àwọn ẹyẹ, 'tànná,
Àti ohun gbogbo,
Kò sì gbàgbé àwọn 'mọ Rẹ̀,
Mo mọ̀, p' Ó fẹ́ràn wọn.

Ó fẹ́ mi náà, Ó fẹ́ mi náà,
Mo mọ̀, Ó fẹ́ mi náà,
'Tọr' Ó fẹ́ ohun kékeré,
Mo mọ̀, Ó fẹ́ mi náà.