Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 493: Yìn Ọlọ́run, Ìbú Oore

Praise God From Whom All Blessings Flow

Yìn Ọlọ́run, ìbú oore;
Ẹ yìn Ín, ẹ̀yin ẹ̀dá ayé,
Ẹ yìn Ín, ẹ̀yin ẹ̀dá ọ̀run,
Yìn Bàbá, Ọmọ, oun Ẹ̀mí.
Àmín.