Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)
Orin 490: Jésù Wá Láàrín Wa
Jesus, Stand Among Us
Jésù wá láàrín wa
L' agbár' àjíǹdé,
K' àkókò 'sìn wa yìí
Lè kún fún ọ̀wọ̀.
Fi Ẹ̀mí Mímọ́ Rẹ̀
S' ọkàn gbogbo wa;
Lé ẹ̀rù oun ẹ̀dùn
Kúrò l' ọkàn wa.
Bẹ́ẹ̀ ni kánmọ́kánmọ́,
L' a ó t' ẹsẹ̀ m' ọ̀nà
A ó máa rètí oòrọ̀
Oj' ayérayé.