Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 485: Ìwọ Ẹni T' Ó Ó Ń Gb' Àdúrà Ọkàn

O Thou Who Heareth Every Heartfelt Prayer

Ìwọ Ẹni t' ó ó ń gb' àdúrà ọkàn.
F' oore-ọ̀fẹ́ Rẹ̀ pèsè ọkàn wa;
'Wọ n' ìyè, ìfẹ́ àt' ìmọ́lẹ̀ wa,
Ṣe wákàtí Ọjọ́ Ìsimi l' àdùn,
Àmín.