Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 484: Jésù Gbọ́ Tiwa

Hear Our Prayer, O Lord

Jésù gbọ́ tiwa,
Gbọ́ àdúrà wa;
Tẹ́tí sílẹ̀ sí wa,
F' àlááfíà fún wa.
Àmín.