Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 386: 'Ódùn K' A Gbékèlé Jésù

'Tis So Sweet To Trust In Jesus

Ódùn k' a gbékèlé Jésù,
K' a sì gbà ọ̀rọ̀ Rẹ gbọ́,
K' a simi lé ìlérí Rẹ.
P' Ọba Àwímáyèhùn ni.

Jésù, Jésù, mo gbékèlé E,
'Tòr' Alẹ́wìlẹ̀ṣẹ̀ ni,
Jésù, Jésù ọ̀wọ́n, gbà wa,
K' a lè gbékèlé Ọ sí i.

Ó dùn k' a gbékèlé Jésù,
Àt' ẹ̀jẹ̀ 'wẹ̀nùmọ́ Rẹ;
K' a f' ìgbàgbọ́ rí sínú Rẹ,
Ìsun 'múláradà ni.

Jésù, Jésù, mo gbékèlé E,
'Tòr' Alẹ́wìlẹ̀ṣẹ̀ ni,
Jésù, Jésù ọ̀wọ́n, gbà wa,
K' a lè gbékèlé Ọ sí i.

Ó dùn k' a gbékèlé Jésù,
K' a dáwọ́ ẹ̀ṣẹ̀ dúró;
K' a r' ìyè, ayọ̀ àlàáfíà,
Àt' ìsimi Jésù gbà.

Jésù, Jésù, mo gbékèlé E,
'Tòr' Alẹ́wìlẹ̀ṣẹ̀ ni,
Jésù, Jésù ọ̀wọ́n, gbà wa,
K' a lè gbékèlé Ọ sí i.

Mo yọ mo ti ń gbékèlé Ọ,
Jésù mi ìyebíye;
Mo mọ̀ pé 'Wọ wà pẹ̀lú mi,
Títí d' òpin ayé mi.

Jésù, Jésù, mo gbékèlé E,
'Tòr' Alẹ́wìlẹ̀ṣẹ̀ ni,
Jésù, Jésù ọ̀wọ́n, gbà wa,
K' a lè gbékèlé Ọ sí i.