Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 382: Mo Ń Gbékèlé

I Am Trusting Thee

Mo ń gbékèlé 'Wọ nìkanṣo
Jésù Olúwa;
Mo gbékèlé Ọ fún 'gbàlà,
Ọ̀fẹ́ ni

Mo gbékèlé Ọ fún 'fìjì
Mo wọlé fún Ọ;
Mo gbékèlé Ọ f' oore-ọ̀fẹ́
Àt' àánú.

Mo gbékèlé Ọ b' Àmọ̀nà:
Wọ l' ó lè tọ́ mi,
T' ó lè fún mi l' ohun gbogbo
Tí mo ń fẹ́.

Mo gbékèlé Ọ Olúwa
Má jẹ́ kí n ṣubú;
Mo gbékèlé Ọ títí laé
F' ohun gbogbo.