Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 342: Ìhìn Náà Ti Dùn Tó Lẹ́t' Àwọn Ẹ̀rọ Mímọ́

How Sweet Are The Tidings

Ìhìn náà ti dùn tó lẹ́t' àwọn ẹ̀rọ mímọ́,
B' ó ti ṣako jìnà sí ilé!
Láìpẹ́ Olùgbàlà yóò fara hàn n' n ògo,
Láìpẹ́ ni 'jọba náà yóò dé.

Ó ń bọ̀ wá
Ó ń bọ̀ láìpẹ́ yìí, mo mọ̀,
Ó ń bọ̀ wá s' ayé yìí lẹ́ẹ̀kan sí i,
Àt' àwọn ẹ̀rọ t' ó rẹ̀, yóò wọ 'nú ògó,
'Gbàt' ó bá dé láti jọba.

Ìbòjì àtijọ́ t' àwọn ẹ̀rọ mímọ́ sùn,
Yóò sì ṣílẹ̀ bí ti àtijọ́;
Àt' ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn t' ó sùn nín' ibú ńlá,
Yóò gbé nín' ayé lẹ́ẹ̀kan sí i.

Ó ń bọ̀ wá
Ó ń bọ̀ láìpẹ́ yìí, mo mọ̀,
Ó ń bọ̀ wá s' ayé yìí lẹ́ẹ̀kan sí i,
Àt' àwọn ẹ̀rọ t' ó rẹ̀, yóò wọ 'nú ògó,
'Gbàt' ó bá dé láti jọba.

Ní Eden l' a ó padé tí a kì yóò pínyà mọ́!
Orin ìràpadà l' a ó máa kọ;
Àwọn t' a a ràpadà, yóò ti ibi, gbogbo wa,
Láti sìn Ọba wọn ọ̀run.

Ó ń bọ̀ wá
Ó ń bọ̀ láìpẹ́ yìí, mo mọ̀,
Ó ń bọ̀ wá s' ayé yìí lẹ́ẹ̀kan sí i,
Àt' àwọn ẹ̀rọ t' ó rẹ̀, yóò wọ 'nú ògó,
'Gbàt' ó bá dé láti jọba.

Alélúyà, Àmín Alélúyà lẹ́ẹ̀kan sí i!
Bá a bá j' olóòótọ́ a, ó wà níbẹ̀;
Máa ṣọ́nà, sì máa rètí títí di ìgbà náà,
Àwa yóò sì dé adé ògó.

Ó ń bọ̀ wá
Ó ń bọ̀ láìpẹ́ yìí, mo mọ̀,
Ó ń bọ̀ wá s' ayé yìí lẹ́ẹ̀kan sí i,
Àt' àwọn ẹ̀rọ t' ó rẹ̀, yóò wọ 'nú ògó,
'Gbàt' ó bá dé láti jọba.