Ìwé Orin Mímọ́ (Yoruba SDA Hymnal)

Orin 11: Yìn Jésù, F' Ògo Rẹ Hàn

Praise the Lord His Glories Show

Yìn Jésù, f' ògo Rẹ hàn,
Alélúyà!
Ẹ̀yin èèyàn Rẹ láyé,
Alélúyà!
Ẹ̀yin Angẹl' Rẹ l' ọ̀run,
Alélúyà!
Gbogb' ẹ̀yin t' ó ní ìfẹ́ Rẹ,
Alélúyà!

K' ọ̀run àt' ayé kọrin,
Alélúyà!
Sọ 'yanu oun 'tọ́yẹ̀ Rẹ,
Alélúyà!
Nígbà gbogbo, n' ibí gbogbo,
Alélúyà!
Ẹ yìn In, ẹ yìn In, títí láé,
Alélúyà!

Yìn Jésù, wá àánú Rẹ,
Alélúyà!
Yìn In fún ìrànlọ́wọ́ Rẹ,
Alélúyà!
Ohun t' Ó ṣe f' ẹ̀nìyàn,
Alélúyà!
'Rànwọ́ wa níp' Ọmọ Rẹ,
Alélúyà!